Ẹ́sítà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkùnrin Júù kan wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Módékáì+ lorúkọ rẹ̀, ó jẹ́ ọmọ Jáírì, ọmọ Ṣíméì, ọmọ Kíṣì, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+ Ẹ́sítà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Módékáì yìí ni alágbàtọ́* Hádásà,* ìyẹn Ẹ́sítà, tó jẹ́ ọmọ arákùnrin bàbá rẹ̀,+ torí kò ní bàbá àti ìyá. Ọ̀dọ́bìnrin náà lẹ́wà gan-an, ìrísí rẹ̀ sì fani mọ́ra, nígbà tí bàbá àti ìyá rẹ̀ kú, Módékáì mú un ṣe ọmọ.
5 Ọkùnrin Júù kan wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Módékáì+ lorúkọ rẹ̀, ó jẹ́ ọmọ Jáírì, ọmọ Ṣíméì, ọmọ Kíṣì, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+
7 Módékáì yìí ni alágbàtọ́* Hádásà,* ìyẹn Ẹ́sítà, tó jẹ́ ọmọ arákùnrin bàbá rẹ̀,+ torí kò ní bàbá àti ìyá. Ọ̀dọ́bìnrin náà lẹ́wà gan-an, ìrísí rẹ̀ sì fani mọ́ra, nígbà tí bàbá àti ìyá rẹ̀ kú, Módékáì mú un ṣe ọmọ.