1 Sámúẹ́lì 12:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀+ nítorí orúkọ ńlá rẹ̀+ àti nítorí pé Jèhófà ti pinnu láti fi yín ṣe èèyàn rẹ̀.+ Àìsáyà 54:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ohun ìjà èyíkéyìí tí wọ́n bá ṣe sí ọ kò ní ṣàṣeyọrí,+Ahọ́n èyíkéyìí tó bá sì dìde sí ọ láti dá ọ lẹ́jọ́ ni wàá dá lẹ́bi. Ogún* àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà nìyí,Ọ̀dọ̀ mi sì ni òdodo wọn ti wá,” ni Jèhófà wí.+
22 Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀+ nítorí orúkọ ńlá rẹ̀+ àti nítorí pé Jèhófà ti pinnu láti fi yín ṣe èèyàn rẹ̀.+
17 Ohun ìjà èyíkéyìí tí wọ́n bá ṣe sí ọ kò ní ṣàṣeyọrí,+Ahọ́n èyíkéyìí tó bá sì dìde sí ọ láti dá ọ lẹ́jọ́ ni wàá dá lẹ́bi. Ogún* àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà nìyí,Ọ̀dọ̀ mi sì ni òdodo wọn ti wá,” ni Jèhófà wí.+