ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Àwọn ọba ayé dúró

      Àwọn aláṣẹ sì kóra jọ*+

      Láti dojú kọ Jèhófà àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.+

  • Sáàmù 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ẹni tó wà lórí ìtẹ́ ní ọ̀run á rẹ́rìn-ín;

      Jèhófà máa fi wọ́n ṣẹ̀sín.

  • Àìsáyà 41:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 O máa wá àwọn tó ń bá ọ jà, àmọ́ o ò ní rí wọn;

      Àwọn tó ń bá ọ jagun máa dà bí ohun tí kò sí, bí ohun tí kò sí rárá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́