Sáàmù 89:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Mo ti rí Dáfídì ìránṣẹ́ mi;+Mo ti fi òróró mímọ́ mi yàn án.+ Àìsáyà 61:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+
61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+