Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Mátíù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Lẹ́yìn tí Jésù ṣèrìbọmi, ó jáde látinú omi lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀; sì wò ó! ọ̀run ṣí sílẹ̀,+ ó sì rí i tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà bọ̀ wá sórí rẹ̀.+
42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
16 Lẹ́yìn tí Jésù ṣèrìbọmi, ó jáde látinú omi lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀; sì wò ó! ọ̀run ṣí sílẹ̀,+ ó sì rí i tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà bọ̀ wá sórí rẹ̀.+