Àìsáyà 52:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ máa fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà. A máa gbé e ga,A máa gbé e lékè, a sì máa gbé e ga gidigidi.+
13 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ máa fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà. A máa gbé e ga,A máa gbé e lékè, a sì máa gbé e ga gidigidi.+