ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 42:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn!

      Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+

      Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+

      Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+

  • Àìsáyà 61:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+

      Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+

      Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,

      Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,

      Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+

  • Fílípì 2:5-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 6 ẹni tó jẹ́ pé, bí ó tiẹ̀ wà ní ìrísí Ọlọ́run,+ kò rò ó rárá pé òun fẹ́ bá Ọlọ́run dọ́gba.+ 7 Ó tì o, àmọ́ ó fi gbogbo ohun tó ní sílẹ̀, ó gbé ìrísí ẹrú wọ̀,+ ó sì di èèyàn.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́