Ìfihàn 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mo gbọ́ tí ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ní báyìí, ìgbàlà+ àti agbára dé àti Ìjọba Ọlọ́run wa+ pẹ̀lú àṣẹ Kristi rẹ̀, torí pé a ti ju ẹni tó ń fẹ̀sùn kan àwọn ará wa sísàlẹ̀, ẹni tó ń fẹ̀sùn kàn wọ́n tọ̀sántòru níwájú Ọlọ́run wa!+
10 Mo gbọ́ tí ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ní báyìí, ìgbàlà+ àti agbára dé àti Ìjọba Ọlọ́run wa+ pẹ̀lú àṣẹ Kristi rẹ̀, torí pé a ti ju ẹni tó ń fẹ̀sùn kan àwọn ará wa sísàlẹ̀, ẹni tó ń fẹ̀sùn kàn wọ́n tọ̀sántòru níwájú Ọlọ́run wa!+