ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 13:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Kí ẹ ṣe èyí nítorí ẹ mọ àsìkò tí a wà, pé wákàtí ti tó fún yín láti jí lójú oorun,+ torí ní báyìí, ìgbàlà wa ti sún mọ́lé ju ti ìgbà tí a di onígbàgbọ́.

  • Hébérù 9:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 bákan náà ló ṣe jẹ́ pé a fi Kristi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé, kó lè ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀;+ tó bá sì fara hàn lẹ́ẹ̀kejì, kò ní jẹ́ torí ẹ̀ṣẹ̀,* àwọn tó ń fi taratara wá a fún ìgbàlà wọn sì máa rí i.+

  • 1 Pétérù 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 tí agbára Ọlọ́run dáàbò bò nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ fún ìgbàlà kan tí a ṣe tán láti ṣí payá ní àkókò ìkẹyìn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́