Àìsáyà 53:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+ Róòmù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí ikú tó kú jẹ́ láti mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò,* ó kú lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní kú mọ́ láé,+ àmọ́ ìgbé ayé tó ń gbé jẹ́ láti máa ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run. 1 Pétérù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó fi ara rẹ̀ ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+ lórí òpó igi,*+ ká lè di òkú sí ẹ̀ṣẹ̀,* ká sì wà láàyè sí òdodo. Ẹ “sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.”+
12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+
10 Nítorí ikú tó kú jẹ́ láti mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò,* ó kú lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní kú mọ́ láé,+ àmọ́ ìgbé ayé tó ń gbé jẹ́ láti máa ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.
24 Ó fi ara rẹ̀ ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+ lórí òpó igi,*+ ká lè di òkú sí ẹ̀ṣẹ̀,* ká sì wà láàyè sí òdodo. Ẹ “sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.”+