ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 20:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Gẹ́gẹ́ bí Ọmọ èèyàn ò ṣe wá ká lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, àmọ́ kó lè ṣe ìránṣẹ́,+ kó sì fi ẹ̀mí* rẹ̀ ṣe ìràpadà ní pàṣípààrọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.”+

  • 1 Tímótì 2:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Torí Ọlọ́run kan ló wà+ àti alárinà kan+ láàárín Ọlọ́run àtàwọn èèyàn,+ ọkùnrin kan, Kristi Jésù,+ 6 ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà tó bá a mu rẹ́gí fún gbogbo èèyàn*+—ohun tí a máa jẹ́rìí sí nìyí tí àkókò rẹ̀ bá tó.

  • Títù 2:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 bí a ti ń dúró de àwọn ohun aláyọ̀ tí à ń retí+ àti bí Ọlọ́run Olódùmarè ṣe máa fara hàn nínú ògo pẹ̀lú Olùgbàlà wa, Jésù Kristi, 14 ẹni tó yọ̀ǹda ara rẹ̀ nítorí wa+ kó lè tú wa sílẹ̀*+ kúrò nínú gbogbo onírúurú ìwà tí kò bófin mu, kó sì wẹ àwọn èèyàn rẹ̀ mọ́, àwọn ohun ìní rẹ̀ pàtàkì, tí wọ́n ní ìtara fún iṣẹ́ rere.+

  • Hébérù 9:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 bákan náà ló ṣe jẹ́ pé a fi Kristi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé, kó lè ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀;+ tó bá sì fara hàn lẹ́ẹ̀kejì, kò ní jẹ́ torí ẹ̀ṣẹ̀,* àwọn tó ń fi taratara wá a fún ìgbàlà wọn sì máa rí i.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́