ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 4:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Yàtọ̀ síyẹn, kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíì, nítorí kò sí orúkọ míì+ lábẹ́ ọ̀run tí a fún àwọn èèyàn tí a lè tipasẹ̀ rẹ̀ rí ìgbàlà.”+

  • Róòmù 5:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àmọ́ ẹ̀bùn náà ò rí bí àṣemáṣe. Torí bó ṣe jẹ́ pé nípa àṣemáṣe ọkùnrin kan ni ọ̀pọ̀ èèyàn fi kú, ẹ wo bí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run àti ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ rẹ̀ nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí ọkùnrin kan,+ ìyẹn Jésù Kristi, ṣe ṣe ọ̀pọ̀ èèyàn láǹfààní!*+

  • 2 Tímótì 1:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ó gbà wá, ó sì fi ìpè mímọ́ pè wá,+ kì í ṣe torí àwọn iṣẹ́ wa, àmọ́ torí ohun tó fẹ́ ṣe àti inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.+ Ọjọ́ pẹ́ tí a ti fún wa ní èyí nípasẹ̀ Kristi Jésù, 10 àmọ́ nísinsìnyí ìfarahàn Olùgbàlà wa, Kristi Jésù,+ ti mú kó ṣe kedere, ẹni tó mú ikú kúrò,+ tó sì tipasẹ̀ ìhìn rere+ tan ìmọ́lẹ̀ sí ìyè+ àti àìdíbàjẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́