Àìsáyà 53:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Mátíù 20:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Gẹ́gẹ́ bí Ọmọ èèyàn ò ṣe wá ká lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, àmọ́ kó lè ṣe ìránṣẹ́,+ kó sì fi ẹ̀mí* rẹ̀ ṣe ìràpadà ní pàṣípààrọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.”+
11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+
28 Gẹ́gẹ́ bí Ọmọ èèyàn ò ṣe wá ká lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, àmọ́ kó lè ṣe ìránṣẹ́,+ kó sì fi ẹ̀mí* rẹ̀ ṣe ìràpadà ní pàṣípààrọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.”+