-
Róòmù 5:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nítorí náà, bó ṣe jẹ́ pé àṣemáṣe kan ló yọrí sí ìdálẹ́bi onírúurú èèyàn,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe jẹ́ pé ìwà òdodo kan ló mú ká pe onírúurú èèyàn+ ní olódodo fún ìyè.+ 19 Nítorí bó ṣe jẹ́ pé àìgbọràn èèyàn kan ló mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn di ẹlẹ́ṣẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ náà ni ìgbọràn èèyàn kan á ṣe mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn di olódodo.+
-