Àìsáyà 53:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Hébérù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí ó yẹ kí ẹni tí ohun gbogbo torí rẹ̀ wà, tí ohun gbogbo sì tipasẹ̀ rẹ̀ wà, bí o ti ń mú ọ̀pọ̀ ọmọ wá sínú ògo,+ sọ Olórí Aṣojú ìgbàlà+ wọn di pípé nípasẹ̀ ìjìyà.+
11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+
10 Torí ó yẹ kí ẹni tí ohun gbogbo torí rẹ̀ wà, tí ohun gbogbo sì tipasẹ̀ rẹ̀ wà, bí o ti ń mú ọ̀pọ̀ ọmọ wá sínú ògo,+ sọ Olórí Aṣojú ìgbàlà+ wọn di pípé nípasẹ̀ ìjìyà.+