Róòmù 8:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí mo gbà pé àwọn ìyà àsìkò yìí kò já mọ́ nǹkan kan tí a bá fi wé ògo tí a máa fi hàn nínú wa.+ 19 Torí ìṣẹ̀dá ń dúró de ìfihàn àwọn ọmọ Ọlọ́run+ lójú méjèèjì. 2 Kọ́ríńtì 6:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “‘Màá di bàbá yín,+ ẹ ó sì di ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mi,’+ ni Jèhófà,* Olódùmarè wí.”
18 Nítorí mo gbà pé àwọn ìyà àsìkò yìí kò já mọ́ nǹkan kan tí a bá fi wé ògo tí a máa fi hàn nínú wa.+ 19 Torí ìṣẹ̀dá ń dúró de ìfihàn àwọn ọmọ Ọlọ́run+ lójú méjèèjì.