ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 22:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 A tú mi jáde bí omi;

      Gbogbo egungun mi ti yẹ̀.

      Ọkàn mi ti dà bí ìda;+

      Ó yọ́ nínú mi lọ́hùn-ún.+

  • Mátíù 26:27, 28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ó mú ife kan, ó dúpẹ́, ó sì gbé e fún wọn, ó ní: “Gbogbo yín, ẹ mu nínú rẹ̀,+ 28 torí èyí túmọ̀ sí ‘ẹ̀jẹ̀+ májẹ̀mú’ mi,+ tí a máa dà jáde nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn,+ kí wọ́n lè rí ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀.+

  • Hébérù 2:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nítorí náà, torí pé “àwọn ọmọ kéékèèké” ní ẹ̀jẹ̀ àti ẹran ara, òun náà wá ní ẹ̀jẹ̀ àti ẹran ara,+ kó lè tipasẹ̀ ikú rẹ̀ pa ẹni tó lè fa ikú run,+ ìyẹn Èṣù,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́