Ẹ́kísódù 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mósè wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn èèyàn náà,+ ó sì sọ pé: “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá pẹ̀lú gbogbo ọ̀rọ̀ yìí.”+ Jeremáyà 31:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá bá ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà dá májẹ̀mú tuntun.+ Hébérù 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jésù wá tipa bẹ́ẹ̀ di ẹni tó fìdí májẹ̀mú tó dáa jù múlẹ̀.*+
8 Mósè wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn èèyàn náà,+ ó sì sọ pé: “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá pẹ̀lú gbogbo ọ̀rọ̀ yìí.”+