Lúùkù 21:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí náà, ẹ máa wà lójúfò,+ kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí ẹ lè bọ́ nínú gbogbo nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ yìí, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ èèyàn.”+ 1 Tẹsalóníkà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí a máa sùn bí àwọn yòókù ti ń ṣe,+ àmọ́ ẹ jẹ́ kí a wà lójúfò,+ kí a sì máa ronú bó ṣe tọ́.+
36 Torí náà, ẹ máa wà lójúfò,+ kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí ẹ lè bọ́ nínú gbogbo nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ yìí, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ èèyàn.”+
6 Torí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí a máa sùn bí àwọn yòókù ti ń ṣe,+ àmọ́ ẹ jẹ́ kí a wà lójúfò,+ kí a sì máa ronú bó ṣe tọ́.+