Mátíù 24:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Torí náà, ẹ máa ṣọ́nà, torí pé ẹ ò mọ ọjọ́ tí Olúwa yín ń bọ̀.+