Mátíù 25:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Torí náà, ẹ máa ṣọ́nà,+ torí pé ẹ ò mọ ọjọ́ tàbí wákàtí náà.+ Máàkù 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ máa wọ̀nà, ẹ wà lójúfò,+ torí ẹ ò mọ ìgbà tí àkókò tí a yàn jẹ́.+ Lúùkù 21:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí náà, ẹ máa wà lójúfò,+ kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí ẹ lè bọ́ nínú gbogbo nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ yìí, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ èèyàn.”+
36 Torí náà, ẹ máa wà lójúfò,+ kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí ẹ lè bọ́ nínú gbogbo nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ yìí, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ èèyàn.”+