Mátíù 25:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Torí náà, ẹ máa ṣọ́nà,+ torí pé ẹ ò mọ ọjọ́ tàbí wákàtí náà.+ Lúùkù 21:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “Àmọ́ ẹ kíyè sí ara yín, kí àjẹjù, ọtí àmujù + àti àníyàn ìgbésí ayé má bàa di ẹrù pa ọkàn yín,+ láìròtẹ́lẹ̀ kí ọjọ́ yẹn sì dé bá yín lójijì
34 “Àmọ́ ẹ kíyè sí ara yín, kí àjẹjù, ọtí àmujù + àti àníyàn ìgbésí ayé má bàa di ẹrù pa ọkàn yín,+ láìròtẹ́lẹ̀ kí ọjọ́ yẹn sì dé bá yín lójijì