Róòmù 13:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí ẹ ṣe èyí nítorí ẹ mọ àsìkò tí a wà, pé wákàtí ti tó fún yín láti jí lójú oorun,+ torí ní báyìí, ìgbàlà wa ti sún mọ́lé ju ti ìgbà tí a di onígbàgbọ́.
11 Kí ẹ ṣe èyí nítorí ẹ mọ àsìkò tí a wà, pé wákàtí ti tó fún yín láti jí lójú oorun,+ torí ní báyìí, ìgbàlà wa ti sún mọ́lé ju ti ìgbà tí a di onígbàgbọ́.