-
Jóòbù 30:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 “Wọ́n ti ń fi mí rẹ́rìn-ín báyìí,+
Àwọn ọkùnrin tí kò tó mi lọ́jọ́ orí,
Àwọn tí mi ò lè gbà kí bàbá wọn
Dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn ajá tó ń ṣọ́ agbo ẹran mi.
-