Nọ́ńbà 16:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ni wọ́n bá wólẹ̀, wọ́n sì sọ pé: “Ọlọ́run, ìwọ Ọlọ́run tó ni ẹ̀mí gbogbo èèyàn,*+ ṣé ẹ̀ṣẹ̀ ẹnì kan ṣoṣo máa wá mú kí o bínú sí gbogbo àpéjọ+ yìí?” Sáàmù 104:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Tí o bá rán ẹ̀mí rẹ jáde, a ó dá wọn,+Ìwọ á sì sọ ojú ilẹ̀ di ọ̀tun. Oníwàásù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà náà, erùpẹ̀ á pa dà sí ilẹ̀,+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ẹ̀mí* á sì pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ tó fúnni.+ Ìsíkíẹ́lì 18:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Gbogbo ọkàn,* tèmi ni wọ́n. Bí ọkàn bàbá ti jẹ́ tèmi, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ọmọ. Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.
22 Ni wọ́n bá wólẹ̀, wọ́n sì sọ pé: “Ọlọ́run, ìwọ Ọlọ́run tó ni ẹ̀mí gbogbo èèyàn,*+ ṣé ẹ̀ṣẹ̀ ẹnì kan ṣoṣo máa wá mú kí o bínú sí gbogbo àpéjọ+ yìí?”
7 Nígbà náà, erùpẹ̀ á pa dà sí ilẹ̀,+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ẹ̀mí* á sì pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ tó fúnni.+
4 Wò ó! Gbogbo ọkàn,* tèmi ni wọ́n. Bí ọkàn bàbá ti jẹ́ tèmi, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn ọmọ. Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.