Sáàmù 50:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 O jókòó, o sì sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí arákùnrin rẹ;+O fi àléébù ọmọ ìyá rẹ hàn.* 21 Nígbà tí o ṣe àwọn nǹkan yìí, mi ò sọ̀rọ̀,Torí náà, o rò pé màá dà bíi tìẹ. Àmọ́ ní báyìí, màá bá ọ wí,Màá sì pè ọ́ lẹ́jọ́.+ Jémíìsì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ tí ẹ bá ṣì ń ṣe ojúsàájú,+ ẹ̀ṣẹ̀ lẹ̀ ń dá, òfin sì ti dá yín lẹ́bi* pé ẹlẹ́ṣẹ̀ ni yín.+
20 O jókòó, o sì sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí arákùnrin rẹ;+O fi àléébù ọmọ ìyá rẹ hàn.* 21 Nígbà tí o ṣe àwọn nǹkan yìí, mi ò sọ̀rọ̀,Torí náà, o rò pé màá dà bíi tìẹ. Àmọ́ ní báyìí, màá bá ọ wí,Màá sì pè ọ́ lẹ́jọ́.+