Sáàmù 50:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó pe ọ̀run lókè, ó sì pe ayé,+Kí ó lè ṣèdájọ́ àwọn èèyàn rẹ̀,+ ó ní: Oníwàásù 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí Ọlọ́run tòótọ́ yóò dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́ lórí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe, títí kan gbogbo ohun tó fara pa mọ́, bóyá ó dára tàbí ó burú.+
14 Nítorí Ọlọ́run tòótọ́ yóò dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́ lórí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe, títí kan gbogbo ohun tó fara pa mọ́, bóyá ó dára tàbí ó burú.+