Míkà 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ gbọ́ ẹjọ́ Jèhófà, ẹ̀yin òkèÀti ẹ̀yin ìpìlẹ̀ ayé tó fìdí múlẹ̀,+Torí Jèhófà fẹ́ pe àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́jọ́;Yóò sì bá Ísírẹ́lì ro ẹjọ́ pé:+
2 Ẹ gbọ́ ẹjọ́ Jèhófà, ẹ̀yin òkèÀti ẹ̀yin ìpìlẹ̀ ayé tó fìdí múlẹ̀,+Torí Jèhófà fẹ́ pe àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́jọ́;Yóò sì bá Ísírẹ́lì ro ẹjọ́ pé:+