1 Sámúẹ́lì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ń pani, ó sì ń dá ẹ̀mí ẹni sí;*Ó múni sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,* ó sì ń gbéni dìde.+ Àìsáyà 57:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Olódodo ṣègbé,Àmọ́ ẹnì kankan ò fi sọ́kàn. Àwọn olóòótọ́ èèyàn ti lọ,*+Ẹnì kankan ò sì fòye mọ̀ pé olódodo ti lọTorí* àjálù náà. 2 Ó wọnú àlàáfíà. Wọ́n sinmi lórí ibùsùn wọn,* gbogbo àwọn tó ń rìn lọ́nà títọ́.
57 Olódodo ṣègbé,Àmọ́ ẹnì kankan ò fi sọ́kàn. Àwọn olóòótọ́ èèyàn ti lọ,*+Ẹnì kankan ò sì fòye mọ̀ pé olódodo ti lọTorí* àjálù náà. 2 Ó wọnú àlàáfíà. Wọ́n sinmi lórí ibùsùn wọn,* gbogbo àwọn tó ń rìn lọ́nà títọ́.