Oníwàásù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bí kò ṣe sí èèyàn tó lágbára lórí ẹ̀mí* tàbí tó lè dá ẹ̀mí dúró, bẹ́ẹ̀ ni kò sẹ́ni tó lágbára lórí ọjọ́ ikú.+ Bí ẹnikẹ́ni kò ṣe lè dá ara rẹ̀ sílẹ̀ lójú ogun, bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú kò ní jẹ́ kí àwọn tó ń hù ú yè bọ́.* Àìsáyà 57:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.
8 Bí kò ṣe sí èèyàn tó lágbára lórí ẹ̀mí* tàbí tó lè dá ẹ̀mí dúró, bẹ́ẹ̀ ni kò sẹ́ni tó lágbára lórí ọjọ́ ikú.+ Bí ẹnikẹ́ni kò ṣe lè dá ara rẹ̀ sílẹ̀ lójú ogun, bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú kò ní jẹ́ kí àwọn tó ń hù ú yè bọ́.*
16 Torí mi ò ní ta kò wọ́n títí láé,Mi ò sì ní máa bínú títí lọ;+Torí àárẹ̀ máa bá ẹ̀mí èèyàn nítorí mi,+Títí kan àwọn ohun tó ń mí, tí mo dá.