Jóòbù 34:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Tó bá fiyè* sí wọn,Tó bá kó ẹ̀mí àti èémí wọn jọ sọ́dọ̀ ara rẹ̀,+15 Gbogbo èèyàn* jọ máa ṣègbé,Aráyé á sì pa dà sí erùpẹ̀.+
14 Tó bá fiyè* sí wọn,Tó bá kó ẹ̀mí àti èémí wọn jọ sọ́dọ̀ ara rẹ̀,+15 Gbogbo èèyàn* jọ máa ṣègbé,Aráyé á sì pa dà sí erùpẹ̀.+