ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 104:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Tí o bá gbé ojú rẹ pa mọ́, ìdààmú á bá wọn.

      Tí o bá mú ẹ̀mí wọn kúrò, wọ́n á kú, wọ́n á sì pa dà sí erùpẹ̀.+

  • Oníwàásù 12:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Nígbà náà, erùpẹ̀ á pa dà sí ilẹ̀,+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ẹ̀mí* á sì pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ tó fúnni.+

  • Àìsáyà 42:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,

      Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+

      Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+

      Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+

      Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+

  • Ìṣe 17:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 bẹ́ẹ̀ ni kì í retí pé kí èèyàn ran òun lọ́wọ́ bíi pé ó nílò ohunkóhun,+ nítorí òun fúnra rẹ̀ ló ń fún gbogbo èèyàn ní ìyè àti èémí+ àti ohun gbogbo.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́