-
Jóòbù 25:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Òṣùpá pàápàá kò mọ́lẹ̀,
Àwọn ìràwọ̀ ò sì mọ́ lójú rẹ̀,
6 Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ẹni kíkú, tó jẹ́ ìdin
Àti ọmọ èèyàn, tó jẹ́ kòkòrò mùkúlú!”
-