ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 11:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ì bá sọ àwọn àṣírí ọgbọ́n fún ọ,

      Torí ọgbọ́n tó gbéṣẹ́ pín sí oríṣiríṣi ọ̀nà.

      O máa wá mọ̀ pé ńṣe ni Ọlọ́run yàn láti gbàgbé àwọn àṣìṣe rẹ kan.

  • Jóòbù 15:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Kí ni ẹni kíkú jẹ́ tó fi máa mọ́,

      Tàbí ẹnikẹ́ni tí obìnrin bí tó fi máa jẹ́ olódodo?+

      15 Wò ó! Kò ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,

      Àwọn ọ̀run pàápàá kò mọ́ ní ojú rẹ̀.+

  • Jóòbù 22:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 “Ṣé èèyàn wúlò fún Ọlọ́run?

      Ṣé ẹni tó ní ìjìnlẹ̀ òye lè ṣe é láǹfààní?+

       3 Tí o bá jẹ́ olódodo, kí ló kan Olódùmarè,*

      Àbí ó jèrè kankan torí pé o rìn ní ọ̀nà ìwà títọ́?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́