-
Jóòbù 32:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Inú tún bí i gidigidi sí àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù mẹ́tẹ̀ẹ̀ta torí wọn ò mọ bó ṣe yẹ kí wọ́n fèsì, àmọ́ wọ́n pe Ọlọ́run ní ẹni burúkú.+