Jóòbù 33:8-10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́, o sọ ọ́ létí mi,Àní mo ṣáà ń gbọ́ tí ò ń sọ pé, 9 ‘Mo mọ́, mi ò ní ẹ̀ṣẹ̀ lọ́rùn;+Mo mọ́, mi ò ní àṣìṣe.+ 10 Àmọ́ Ọlọ́run rí ìdí tó fi yẹ kó ta kò mí;Ó kà mí sí ọ̀tá rẹ̀.+
8 Àmọ́, o sọ ọ́ létí mi,Àní mo ṣáà ń gbọ́ tí ò ń sọ pé, 9 ‘Mo mọ́, mi ò ní ẹ̀ṣẹ̀ lọ́rùn;+Mo mọ́, mi ò ní àṣìṣe.+ 10 Àmọ́ Ọlọ́run rí ìdí tó fi yẹ kó ta kò mí;Ó kà mí sí ọ̀tá rẹ̀.+