ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 10:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 O mọ̀ pé mi ò jẹ̀bi,+

      Kò sì sí ẹni tó lè gbà mí lọ́wọ́ rẹ.+

  • Jóòbù 16:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ojú mi ti pọ́n torí mò ń sunkún,+

      Òkùnkùn biribiri* sì wà ní ìpéǹpéjú mi,

      17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọwọ́ mi ò hùwà ipá kankan,

      Àdúrà mi sì mọ́.

  • Jóòbù 23:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ẹsẹ̀ mi tẹ̀ lé àwọn ìṣísẹ̀ rẹ̀ pẹ́kípẹ́kí;

      Mò ń rìn ní ọ̀nà rẹ̀ ṣáá, mi ò sì yà kúrò níbẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́