Sáàmù 119:165 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 165 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà jẹ́ ti àwọn tó nífẹ̀ẹ́ òfin rẹ;+Kò sí ohun tó lè mú wọn kọsẹ̀.*