ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 1:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ṣùgbọ́n òfin Jèhófà máa ń mú inú rẹ̀ dùn,+

      Ó sì ń fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka* òfin Rẹ̀ tọ̀sántòru.+

       3 Ó máa dà bí igi tí a gbìn sétí odò,

      Tó ń so èso ní àsìkò rẹ̀,

      Tí ewé rẹ̀ kì í sì í rọ.

      Gbogbo ohun tó bá ń ṣe yóò máa yọrí sí rere.+

  • Òwe 3:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ọmọ mi, má gbàgbé ẹ̀kọ́* mi,

      Sì jẹ́ kí ọkàn rẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́,

       2 Nítorí wọ́n á fi ọ̀pọ̀ ọjọ́

      Àti ẹ̀mí gígùn pẹ̀lú àlàáfíà kún un fún ọ.+

  • Àìsáyà 32:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àlàáfíà ni òdodo tòótọ́ máa mú wá, +

      Èso òdodo tòótọ́ sì máa jẹ́ ìparọ́rọ́ àti ààbò tó máa wà pẹ́ títí.+

  • Àìsáyà 48:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ká ní o fetí sí àwọn àṣẹ mi ni!+

      Àlàáfíà rẹ ì bá dà bí odò,+

      Òdodo rẹ ì bá sì dà bí ìgbì òkun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́