ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 19:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+

      Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+

  • Sáàmù 40:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,*+

      Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+

  • Sáàmù 112:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 112 Ẹ yin Jáà!*+

      א [Áléfì]

      Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+

      ב [Bétì]

      Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+

  • Mátíù 5:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run,*+ torí Ìjọba ọ̀run jẹ́ tiwọn.

  • Róòmù 7:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nínú mi lọ́hùn-ún,+ mo nífẹ̀ẹ́ òfin Ọlọ́run gan-an,

  • Jémíìsì 1:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́