Sáàmù 1:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Aláyọ̀ ni ẹni tí kì í tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn èèyàn burúkúTí kì í dúró ní ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀+Tí kì í sì í jókòó lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́gàn.+ 2 Ṣùgbọ́n òfin Jèhófà máa ń mú inú rẹ̀ dùn,+Ó sì ń fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka* òfin Rẹ̀ tọ̀sántòru.+ Sáàmù 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,*+Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+
1 Aláyọ̀ ni ẹni tí kì í tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn èèyàn burúkúTí kì í dúró ní ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀+Tí kì í sì í jókòó lọ́dọ̀ àwọn ẹlẹ́gàn.+ 2 Ṣùgbọ́n òfin Jèhófà máa ń mú inú rẹ̀ dùn,+Ó sì ń fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka* òfin Rẹ̀ tọ̀sántòru.+