Sáàmù 119:72 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 72 Òfin tí o kéde dára fún mi,+Ó dára ju ẹgbẹẹgbẹ̀rún wúrà àti fàdákà lọ.+