Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+ Sáàmù 19:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n yẹ ní fífẹ́ ju wúrà,Ju ọ̀pọ̀ wúrà tó dáa,*+Wọ́n sì dùn ju oyin lọ,+ oyin inú afárá. Òwe 3:13-15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+Àti ẹni tó ní òye;14 Kéèyàn ní in sàn ju kéèyàn ní fàdákà,Kéèyàn jèrè rẹ̀ sì sàn ju kéèyàn jèrè wúrà.+ 15 Ó ṣeyebíye ju iyùn* lọ;Kò sí ohun míì tí o fẹ́ tó ṣeé fi wé e.
7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+
13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+Àti ẹni tó ní òye;14 Kéèyàn ní in sàn ju kéèyàn ní fàdákà,Kéèyàn jèrè rẹ̀ sì sàn ju kéèyàn jèrè wúrà.+ 15 Ó ṣeyebíye ju iyùn* lọ;Kò sí ohun míì tí o fẹ́ tó ṣeé fi wé e.