-
Àìsáyà 66:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
Ẹ máa mu ọmú, a máa gbé yín sí ẹ̀gbẹ́,
Wọ́n á sì máa bá yín ṣeré lórí orúnkún.
-
12 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
Ẹ máa mu ọmú, a máa gbé yín sí ẹ̀gbẹ́,
Wọ́n á sì máa bá yín ṣeré lórí orúnkún.