Àìsáyà 60:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn orílẹ̀-èdè máa lọ sínú ìmọ́lẹ̀ rẹ,+Àwọn ọba+ sì máa lọ sínú ẹwà rẹ tó ń tàn.*+ Hágáì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “‘Èmi yóò mi gbogbo orílẹ̀-èdè jìgìjìgì, àwọn ohun iyebíye* nínú gbogbo orílẹ̀-èdè yóò sì wọlé wá;+ èmi yóò sì fi ògo kún ilé yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
7 “‘Èmi yóò mi gbogbo orílẹ̀-èdè jìgìjìgì, àwọn ohun iyebíye* nínú gbogbo orílẹ̀-èdè yóò sì wọlé wá;+ èmi yóò sì fi ògo kún ilé yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.