Àìsáyà 49:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn ọba máa di olùtọ́jú rẹ,+Àwọn ọmọ wọn obìnrin sì máa di alágbàtọ́ rẹ. Wọ́n máa tẹrí ba fún ọ, wọ́n á sì dojú bolẹ̀,+Wọ́n máa lá iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ,+Wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà;Ojú ò ní ti àwọn tó bá gbẹ́kẹ̀ lé mi.”+
23 Àwọn ọba máa di olùtọ́jú rẹ,+Àwọn ọmọ wọn obìnrin sì máa di alágbàtọ́ rẹ. Wọ́n máa tẹrí ba fún ọ, wọ́n á sì dojú bolẹ̀,+Wọ́n máa lá iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ,+Wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà;Ojú ò ní ti àwọn tó bá gbẹ́kẹ̀ lé mi.”+