Àìsáyà 60:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn ọmọ àwọn tó fìyà jẹ ọ́ máa wá, wọ́n á sì tẹrí ba níwájú rẹ;Gbogbo àwọn tó ń hùwà àfojúdi sí ọ gbọ́dọ̀ tẹrí ba níbi ẹsẹ̀ rẹ,Wọ́n sì máa pè ọ́ ní ìlú Jèhófà,Síónì Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.+
14 Àwọn ọmọ àwọn tó fìyà jẹ ọ́ máa wá, wọ́n á sì tẹrí ba níwájú rẹ;Gbogbo àwọn tó ń hùwà àfojúdi sí ọ gbọ́dọ̀ tẹrí ba níbi ẹsẹ̀ rẹ,Wọ́n sì máa pè ọ́ ní ìlú Jèhófà,Síónì Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.+