-
Jóòbù 9:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àwọn ọjọ́ mi wá ń yára ju ẹni tó ń sáré;+
Wọ́n sá lọ láìrí ohun tó dáa.
-
-
Àìsáyà 38:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mo sọ pé: “Ní àárín ọjọ́ ayé mi,
Mo gbọ́dọ̀ wọnú àwọn ẹnubodè Isà Òkú.*
A máa fi àwọn ọdún mi tó kù dù mí.”
-