Sáàmù 102:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ọjọ́ mi dà bí òjìji tó ń pa rẹ́ lọ,*+Mo sì ń rọ bíi koríko.+ Sáàmù 103:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ti ẹni kíkú, àwọn ọjọ́ rẹ̀ dà bíi ti koríko;+Ó rú jáde bí ìtànná orí pápá.+ Sáàmù 144:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èèyàn dà bí èémí lásán;+Àwọn ọjọ́ rẹ̀ dà bí òjìji tó ń kọjá lọ.+