Jóòbù 14:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+
14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+